YO/Prabhupada 0095 - Ise wa ni lati jowo ara wa
Lecture on BG 4.7 -- Bombay, March 27, 1974
A nse teriba, sugbon a ko fi ara wa fun Olorun. Arun na ni yi. Aarun na ni yi. Isokan Olorun si tumo si ka se iwosan aarun na. E se iwosan aarun yi. Olorun na wa. O so wipe, yadā yadā hi dharmasya (BG 4.7). Dharmasya glaani na, aise dede nipa eto esin, nigbati aise dede ba wa, Olorun so wipe, tadātmānaṁ sṛjāmy aham. Ati abhyutthānam adharmasya. Nkan meji lowa nbe. Nigbati awon eniyan o ba fi ara won fun Olorun, won a da opolopo "Olorun" sile, opo awon alaibikita, jowo ara won nibe. Iyen ni adharmasya. Dharma tumo si lati fi ara wa fun Olorun, sugbon kaka ti won ba fi ara won fun Olorun, won fi ara won fun awon ologbo, awon aja, eyi, t'ohun, awon orisiris nkan. Iyen ni adharma.
Olorun o wa lati da esin karohun-wi Hindu, tabi esin Musulumi, tabi esin omo-eleyin Kristi sile. Rara. O wa lati esin olododo sile Esin olododo tumo si pe a ni lati fifun, lati fi ara fun eni o tito. Iyen ni esin olododo. A nteribale. Olukaluku ni iye kan. O si ti jowo ara re sibe. Koda bi onse ti iselu, ti elegbe, nipa ti oro-aje, ti esin, ohun kohun. Oloukaluku ni iye kan. Olori apeere na si wa nbe. Bee na ise wa ni lati jowo ara wa. Iyen je ododd. Sugbon a o mo ibiti a ni lati jowo ara wa. Iyen ni isoro. Ati wipe bi iteribale na se je asise tabi fi sipo ti ko to, nitori idi eyi ni gbogbo aye se wa ni rudurudu.
A nse ayipada iteribale yi fun iteribale miran. A o fe egbe oselu Congree mo. Nissinyi egbe oselu Communist ni. To ba tun ya, "A o fe egbe oselu Communist mo... Egbe oselu yi, egeb oselu t'ohun." Kini iwulo a ti ma yi egbe oselu kan pada si miran? Nitoripe egbe oselu yi tabi imiran, won o se iteribale fun Olorun. Bee ni ayafi ti e ba wa si ipo ati fi ara yin fun Olorun, ko le si ifaya bale kankan. Bo se ri ni yen. Ki a kan ma kuro ninu ikoko obe ki atun fori jona ko le gba ni sile. Nitorina imoran ikeyion Olorun ni wipe:
- sarva-dharmān parityajya
- mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja
- ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
- mokṣayiṣyāmi...
- (BG 18.66)
Bee ni aise dede esin tumo si... Eyi na je sise mimo ninu Srimad Bhagavatam. Sa vai puṁsāṁ paro dharmaḥ. Nipo kini tabi dharma to gaju. Parah tumo si gaju, daraju nkan ti aye yi lo. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). Ti a ba fi ara wa fun Adhoksaja... Adhoksaja tumo si imole to gaju lo, Olorun. Oruko miran fun Olorun ni Adhoksaja. Ahaituky apratihatā. Ahaituki tumo si lai ni idi. Lai ni idi rara. Ki se wipe "Olorun je bayi bayi, nitorina mo jowo ara mi." Rara. Lai ni di. Ahaituky apratihatā. Bee ni lo se wa. Ko si eni to le wadi. Ti e ba fe fi ara yin fun Olorun, ko si iwadi, ko si idaduro kankan. E le se nipo ki po ti e ba wa. E le se. Ahaituky apratihatā yayātmā suprasīdati. Nigba na ni e ma, ātmā, emi yin, ātmā yin, ara yin o ni itelorun. Eyin ni ona na.