YO/Prabhupada 0098 - E je ki ewa Krishna fa yin mora
The Nectar of Devotion -- Vrndavana, November 11, 1972
Madana-mohana. Madana tumo si ifanimora fun ibaralo. Madana, ifanimora ibaralo, Cupid, a si npe Krishna na ni Madana-mohana. Eniyan le, ka wi pe, fi ifanimora ibaralo sile ti Olorun ba fa ni l'okan. Idanwo na ni yen. Madana nfa won mora ninu aye yi. Gbogbo eniyan ni ibaralo nfa mora. Gbogbo ile aye wa lori bibaralo. Otito oro ni yi. Yan maithunādi-gṛhamedhi-suhkhaṁ hi tuccham (SB 7.9.45). Nibi, idunnu, karohun-wi idunnu ni maithuna, maithunaadi. Maithunādi tumo si idunnu nibi beere lati maithuna, ibaralo larin okunrin ati obinrin. Lakopo, awon eniyan..., okunrin kan fe aya. Ero na lati se ite-lorun ife ibaralo. Nigbana lo ma bi awon omo. Nigbana lekansi, nigbati awon omo ba dagba, awon na, omo obinrin a seyawo pelu odomo -kunrin miran, omo okunrin na a fe obinrin miran. Ero kanna ni: ibaralo. Nigbana nko, awon omo omo. Ni sise bayi, idunnu aye - śriyaiśvarya-prajepsavaḥ. Lojo kan koja a ns'allaye. Śrī tumo si èwà, aiśvarya tumo si ola, prajā si tumo si iràn. Bee na nigbakugba, ni awon eniyan feran re - idile to dara, owo ipamo ni banki to dara, ati aya to dara, omo obinrin to dara, omo obinrin ana. Ti idile kan ba wa ti won ni awon obinrin elewa ati ôrô, Ati bo se daju..., opo omo, o gbodo je eni ti o ni se yori. O gbodo je eni ti o ni yori julo. Bee ni śāstra bere wipe, "Kini aseyori yi? Aseyori yi bere pelu ibaralo. Ko ju yen lo. ki won si ma s'abojuto won." Bee ni yan maithunādi-gṛhamedhi-sukhaṁ hi tuccham (SB 7.9.45). Nibi idunnu bere pelu ibaralo, maithunadi. A le ponle ni ona miran, sugbon maithuna yi, idunnu ibaralo, wa nbe lodo awon elede. Awon elede na, won njeun in gbogbo igba, bibi l'ohun: "Nibo ni igbe wa? Nibo ni igbe wa?" won si nbara won lo laisi iyato. Awon elede o nse yato boya mama, anti tbi omo obinrin. Nitori idi eyi, śāstra so wipe, "Nibi, ninu aye yi, a wa ni idande, a wa ninu ewon ninu aye yi fun ibaralo nikan." Iyen ni Cupid. Cupid ni orisa ife, Madana. Ayafi ti eniyan, ki la npe, se dari pelu Madana, Cupid na, ko le se, bi mo se fe wi, inu didun si ibaralo. Oruko Olorun na si ni Madana-mohana . Maadana-mohana tumo si wipe eni ti o ba fa mo Olorun, oluwa re a gbagbe igbadun ife ibaralo. Idanwo na ni yi Nitorina ni oruko Re nje Mādana-mohana. E wo Maadana-mohana. Sanātana Gosvāmī se esin Mādana-mohana. Madana tabi Mādana. Mādana tumo si di were. Madana na, ni Cupid.
Bee ni gbogbo eniyan se nni ikanju agbara ibaralo. Opolopo ibi lo wa... Iwe mimo Bhagavatam so wipe, puṁsaḥ striyā mithunī-bhāvam etat tayor mitho hṛdaya-granthim āhur. Gbogbo aye nyi lo: okunrin nfa obinrin mora, obinrin na nfa okunrin mora. Bi won se nwa ara, ti won ba si ti dapo, isomo-ra won fun igbesi aye yi a di pupo si. Nipa eyi, ti won ba di darapo, tabi leyin ti won ba ti fe ra, obinrin kan ati okunrin, won ma wa ile to dara, grha; kshetra, awon ise, oro-ajé, ile-isè, tabi oko agbe. Nitoripe a gbodo sise-owo. Lat ri ounje je. Gṛha-kṣetra; suta, awon omo,; ati aapta; awon ore; vittah, ôrô. 06:49 Ataḥ gṛha-kṣetra-sutāpta-vittair janasya moho 'yam (SB 5.5.8). Ifamora ti aye yi di lile pupo pupo. Eyi ni anpe ni madana, ifamora ti madana. Sugbon ise wa ki se ki pe ki a je ki nkan didan ti aye fa wa mora. sugbon ki a je ki Olorun fa wa mora. Iyen ni egbe isokan ti Krishna. Ayafi ti ewa Krishna ba fa yin mora, a ni lati ni itelorun nipa ewa asan ti aye yi. Nitorina, Śrī Yamunācārya so wipe: yadāvadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravindayor nava-nava-dhāma rantum āsīt: "Titi igba ti ewa Olorun ti fa mi, ti mo si ti bere si sin ese Re to bi ododo ojuoro, ti mo si nni agbara titun titun, lati igba na, gbere ti mo ba ti ni ero ibalo pelu obinrin, a se mi leebi. Iyen ni vitsnaa, ko si ifanimora mo... Nkan ifanimora to se pataki julo ninu aye yi ni ibaralo, ti enikan, ti eniyan ba fi owo ibaralo sile... Tadāvadhi mama cetaḥ...,
- yadāvadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravindayor
- nava-nava-(rasa-)dhām(anudyata) rantum āsīt
- tadāvadhi bata nārī-saṅgame smaryamāne
- bhavati mukha-vikāraḥ suṣṭu niṣṭhīvanaṁ ca
"Gbere ti mo ba ni ero ibaralo pelu obinrin, lese kanna enu mi a yi si odi a si se mi leebi." Bee na ni Krishna je Madana-mohana. Madana nfa gbogbo eniyan, si ibaralo, Olorun na, ti a ba ni ifamora Olorun, nigbana ni madana o ni iparun. Bee na gbere ti madana ba ti ni iparun, a ti ni isegun lori aye yi. Bibeko ise to soro ni.