YO/Prabhupada 0369 - My disciples They are Part and Parcel of Me



Room Conversation with Life Member, Mr. Malhotra -- December 22, 1976, Poona

Mr. Malhotra: Bawo loseje pe opolopo ninu awon aalufa ni aye igbayen, gbogbo wa sowipe ahaṁ brahmāsmi. Prabhupada: (ede Hindi) Brahman ni yin. Nitoripe nkankanna leje pelu Parabrahman. Moti salaye tele, pe.. Wura, koo ba tobi tabi ko kere, wura loje. Gege na, Bhagavān Parabrahman, nkankanna laje pelu re. Nitorina Brahman nimi. Sugbon Parabrahman ko nimi. Arjuna ti gba pe Parabrahman ni Krsna je: paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). Parabrahman. Gege na param, oro yi lon lo, Paramātmā, Parabrahman, Parameśvara. kilode? Iyato wa. Olori ni ikan je, iranse ni keji je. Brahman to keresi. Brahman leyin je, kejo nibe. Sugbon Parabrahman ko. Teyin ba je Parabrahman, kilode teyin sen se sadhana lati di Parabrahman Kilode? Teyin ba je Parabrahman, Parabrahman lema je ni gbogbo igba. Bawo lese bosinu ipo yi to jepe egbudo se sadhana lati di Parabrahman? Iranu niyen. Parabrahman ko leje. Brahman leje. Wura niyin, kekere. Eyin o le sowipe "ile wura" nimi. Eyin o le sobe. Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). Gopāla Kṛṣṇa: o fe mo boya asiko ti ya lati lo. Seyin ma wa pelu wa na? O daa gan. Prabhupada: Emu omi die wa. Awon akeko mi wanyi, nkankana lonje pelu mi. Ilosiwaju egbe wa yi, awon lon se. Sugbon ton ba sowipe, ipo kanna nimi emi ati Guru Maharaj mi ni, asise niyen je. Mr. Malhotra: Nigbami guru lefe ki awon akeko re ni aseyori ju oun lo. Prabhupada: Itumo iyen ni wipe, awon akeko na o ga to . Egbudo gbabe na. Mr. Malhotra: Gege bi gbogbo baba laye yi ma ri pe awon omo re dagba. Prabhupada: Beeni, sugbon baba ni baba je, omode o le gba aye baba re. Mr. Malhottra: Baba ni baba je sugbon o ma rowipe .... Prabhupada: Rara, rara. Baba a fe ri pe omo re ni ipo laaye to dato ti e, sugbon baba ni baba je, omo l'omo je. Nkan to wa niyen. gege na eyan to je nkankanna pelu Olorun le l'agbara, sugobn iyen o wipe O ti d'Olorun. Mr. Malhotra: Awon asa imi, nigbami awon akeko ma di guru, guru asi d'akeko. Awon iyipada yi wa. Prabhupada: Kole si iyipada. ton ba fe fi guru imi si aye na, akeko le sise na, sugbon iyen o wipe o ti ni ipo kankan pelu guru re. Beeko loje. Mr. Malhotra: Nkan ti mon ro niwipe, Swamiji, Guru yin lon se iwaasu yin latinu yin, eyin na den se 'waasu lati awon akeko yin. Prabhupada: Beeni Mr. Malhotra: Guru niawon akeko je nitoripe guru wa ninu wan. Prabhupada: O daa be. Evaṁ paramparā prāptam (BG 4.2). Sugbon iyen o wipe wan ti di'kan... O le je asoju guru, asoju Olorun, sugbon iyen o wipe oti d'Olorun. Mr. Malhotra: Sugbon odi guru pelu awon akeko re. Prabhupada: O da bee. Mr. Malhotra: kole je egbe pelu guru. Prabhupada: egbe re ko, asoju loje. Egbe re ko. Mole ran okurin kan ko asoju mi, o si le mo nkan se gan, kosi mo nipa eto oro-aje, sugbon kole da to mi. on sise bi asoju mi, nkan imi niyen. Konsepe eni na ti di Olohun ise na. Mr. Malhotra: fun awon akeko yin, guru leje. Prabhupada: Sugbon wan o le sowipe wan ti d'egbe pelu mi. " Moti wa lori ipo kanna pelu guru mi." Wan o le sobe. gege bi omo-okurin yi ton teriba. O le mo bonse sewaasu ju i lo, sugbon o mope mo kere si oga mi." Bibeko kilode ton sen dobaale? O le rowipe, " nisin moti logbon gan. Moti ni ilosiwaju gan. Kilode ti mosefe gba bi oga? Rara. iyen na ma lobayi Lehin igba tin ba tie ku, asi dobaale si aworan mi, Mr. Malhotra: Sugbon laarin awon akeko yin, wa si teriba fun Prabhupada: O daa be, sugbon akeko loje si guru re. Kole sowipe " Nisin moti di guru, kosi nkan to kan mi pelu guru mi mo." Kole so be. gege bi mon sen se, sugbon mo sin saadura si guru mi. gege bayi mosi kere si guru mi, nigba gbogbo. Moti di guru sugbon, mosi kere si guru mi.