YO/Prabhupada 0376 - The Purport to Bhajahu Re Mana



Purport to Bhajahu Re Mana -- Los Angeles, January 7, 1969

Bhajahū re mana, śrī-nanda-nandana-abhaya-caraṇāravinda re. Govinda dasa, lo ko orin yin, akewi to ga gan ati vaisnava loje. Ninu Bhagavad-gita wan sowipe teba ni idari lori okan yin, okan ma je ore yin. sugbon teyin o ba ni idari lori okan yin, ota to gaju loma je. Awan' sa tele awon ore tabi ota, sugbon awon mejeji wa ninu wa. taba le lo ore okan wa, lehin na a le gunke sori ipo to gaju. Sugbon t'okan wa ba d'ota wa, ona wa si orun-apadi ma daju. Nitorina Govinda dāsa Ṭhākura, sin ba okan re wi. Awon yogi sin gbiyanju lati ni idari lori okan wan pelu awon adase. Eyan le se bayi na. Sugbon asiko to po loma gba, nigbami iloseyin lewa. Nigbagbogbo gan ni ikoseyin mawa. Awon yogi nla bi Viśvāmitra, oun na si ni iloseyin, kama wa so pelu awon oniranu yogi wanyi.

gege na Govinda dasa ti fun wa ni imoran wipe " E fokan yin si imoye Krsna. Lehin na okan wa joko sibi kan." ti okan wa o ba ni aye imi lati sise kankan tabi ti Krsna, lehin na kole d'ota mi. Lesekese loma d'ore mi. Ilana ninu Śrīmad-Bhāgavatam: sa vai manaḥ kṛṣṇa-padāravindayoḥ (SB 9.4.18). Oba Ambarīṣa, ni alakoko o f'okan re sori Krsna. gege na, Govinda dāsa Ṭhākura sin bere lowo okan re: " Okan mi, sise fun abhaya-caraṇāravinda." Oruko ese Krsna todani ododo niyen. Laini iberu nitumo Abhaya. teba sini idaabo ese Krsna yi to bi ododo lehin na lesekese lema deyan tio kin beru. Gege na imoran mi wipe " Okan mi sise fun Govinda." Bhajahū re mana śrī-nanda-nandana. Ko p'oruko "Govinda." O pe Krsna ni " omo Nanda Maharaja." " Nitoripe ese re to dabi ododo yi ko kin beru nkankan, eyin na o ni beru maya mo."

Oh mosi fe gbadun awon nkan orisirisi, bawo ni mo sefe gbokan le Krsna?" Govinda si fun ni imoran, "Rara,rara." Durlabha mānava-janma. " ma lo ile aye re ni ilokulo. Ile ae eda yi soroo lati ni. lehin aimoye ibimo loti l'aye yi." Durlabha mānava-janama sat-saṅge. " Nitorina ema losi'bikankan E wa pelu awon elesin." Taraha ei bhava-sindhu re." lehin na ele soda odo ile aye yi." "Oh, tin ba gbokan le Krsna ni gbogbo igba, bawo ni moefe gbadun awon nkan bi awom ebi mi?" Gege na Govinda sowipe, ei dhana yauvana. "" Efe gbadun ola ati ojo odo teni," ei dhana yauvana, putra parijana, " esi fe gbadun awon awujo ore, ife at'ebi, sugbon mo sowipe, "ithe ki āche paratīti re, " seyin rowipe igbadun to daju wa ninu awon nkan wanyi? Rara, kosi nkankan. Itanraeni loje." Ei dhana yauvana, putra parijana, ithe ki āche paratīti re. Durlabha mānava-janama sat-saṅge, taraha ei bhava sindhu re.

śīta ātapa bāta bariṣaṇa
ei dina jāminī jāgi 're
viphale sevinu kṛpaṇa durajana
capala sukha-laba lāgi' re

Govinda sin ran okan re leti " O si mobi ile aye re seri. itumo ile aye yi ni, imo ako ati abo ni ipinnu ile aye yi. Sugbon se'wo o le ranti pe fun igba die lole gbadun imo ako ati abo yi?" Capala. " ko daju. fun igbadie.Otan. Sugbon kilode teyin sen sise to lee bayi?" Śīta ātapa. " Ma ronu nipa yinyin, tabi oru. Ma ronu nipa omi ojo, ma ronu nipa ise ale. On sise lat'aro daale, kini abayo to wa nibe? Fun igbadun igba die yi. Se wo o ni itiju? śīta ātapa, bāta bariṣaṇa, ei dina jāminī jāgi re. Ojo nitumo Dina, ale nitumo jamini. gege na "laaro dale, iwan sise to le bayi? Capala sukha-laba lāgi' re. " Fun igbadun tio daju." Lehin na o sowipe, ei dhana yauvana, putra parijana, ithe ki āche paratīti re. "Kosi igbadun kankan ninu aye yi, tabi ninu ojo odo tabi ebi, awujo. Kosi idunnu kankan."

Nitorina kamala-dala-jala, jīvana ṭalamala. " eyin o de mo fun igba melo lema gbadun aye yi. nitoripe ko daju. E wa lori nkan tio daju. Gege bi omi to wa lori ewe. Eyikeyi asiko lole wo lule. Bi ile aye wa se ri niyen. eyikeyi asiko o le wo lule. A le ba alebu kan , o paari niyen. Ema lo aye yi nilokulo. " Bhajahū hari-pada nīti re. "E sise ninu imoye Krsna nigbogbo igba. Ilosiwaju aye yin niyen." Bawo lese le sise ninu imoye Krsna na? O si fun wa ni imoran, smaraṇa vandana, pāda-sevana dāsya re. E le mu ikan ninu awon ona mesan lati sise ifarafu Olorun. Teba lese gbogbo wan oda be. Teyin o bale se gbogbo awon mejo tan, ele se mesan tabi mefa tabi marun, tabi merin ninu wan. Teba si mu ikan pere ninu wan, ile aye yin mani ilosiwaju. kini awon ona mesan wanyi? Śravaṇaṁ kīrtanam. Igboran lati awon oludari, ati orin kiko. Śravaṇaṁ kīrtanam. Smaraṇam. iranti, Vandanam, adura. Śravaṇa kīrtanaṁ, smaraṇaṁ vandana, pāda-sevanam. ka sise fun Olorun bi iranse re tayeraye. Pūjana sakhī-jana. tabi kesi nife Krsna bi ore yin. Ātma-nivedana. tabi ke fun Krsna ni gbo gbo nkanteba ni Ona ise ifarafun Olorun niyen, Govinda dasa si fe sise ninu imoye Krsna yi.