YO/Prabhupada 0390 - The Purport to Jaya Radha-Madhava



Purport to Jaya Radha-Madhava -- New York, July 20, 1971

gege bi Krsna se je leleyi, gegebi Krsna seje leleyi. Rādhā-Mādhava loje. Ololufe Śrīmatī Rādhārāṇī. ati kuñja-vihārī, ton gbadun asepo pelu awon gopi, ninu awon aginju Vrndavana. Rādhā-mādhava kuñja-vihārī. Ololufe Rādhārāṇī nikan ko loje, sugbon braja-jana-vallabha. Awon olugbe Vrndavan, wan ni'fe Krsna. Wan o mo nkan imi ju Krsna. Wan o si mo boya Olorun ni Krsna, tabi bee ko; kode si itju fun pe " ti Krsna ba je Olorun masi nife re." " O le je Olorun, ko kan wa. Awa fe ni'fe Krsna. Otan. Ife tio ni afikun kankan. "Ti Krsna baje Olorun ma nife fun" - ife pelu afikun leleyi. Ife gidi ko leleyi. Krsna le je Olorun tabi ounkoun toba je, pelu awon ise iyanu ton se, awon Vrajavasi, man ronu bayi, "Oh Krsna, Iyanu omode loje, boya orisa kan. Boya orisa kan." Nitoripe awon eyan man rowipe awon orisa lon l'agbara ju. Wan lagbara ninu ile aye yi. Sugbon won o mowipe Krsna gaju gbogbo won lo. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1). orisa to gaju Brahma, ti sowipe, " Krsna ni Oludari to gaju."

Beena awon olugbe Vrndavan feran Krsna lat'okan wan, gege na, Krsna si feran wa. Vraja-jana-vallabha giri-vara-dhārī. Nigbati awon olugbe Vrndavana fi ipaari si Indra-yajna, alebu nla lo da sile funwon, Inu si bi Indra, osi ran sanma to lagbara gan si won, ojo si ro lai paari fun ojo meje, nigbati awon olugbe Vrndavana bere sini beru, Krsna, omo odun meje nigbana, si fun gbogbo won ni idaado pelu ori-oke Govardhana to gbe soke. O si ko Indradeva, toje orisa, pe "Pelu ika owo kekere mi nimolo lati fi ipaari si gbogbo idamu ton se yi. Otan." O si wa kunle fun Krsna. Gbogbo itan wan yi wa ninu iwe Krsna. Gege bi Gopī-jana-vallabha, ise kan soso toni, ni lati toju awon gopi-jana. Beena ise wa ninu egbe imoye Krsna yi ni basele di gopi-jana. Krsna a si funwa nigbala lati awon alebu, toba tie jepe o ma gbe ori-oke tabi ipata soke. Krsna si daara gan o si lagbara gan. Nigbati Krsna gbe ori-oke yi soke, kose yoga kankan. Olorun niyen. Botilejepe omode loje, ton huwa bi omode, sugbon nigbati asiko na de osi sise re bi Olorun. Krsna niyen. Krsna niyen, kon sepe ogodo lo keko yoga lehin na a d'Olorun. Rara. Iru Olorun bayi ko loje, Olorun ton daa le. Olorun loje.

Beena gopī-jana-vallabha giri-vara-dhārī. Bi omode, omo taya Yaśodā, Yaśodā-nandana,... Krsna feran lati d'omode awon olufokansi. O si fe ki awon ebi re kigbe mo. Nitoripe gbogbo eyan lon s'adura si, koseni ton kigbemo, inu re man dun ti awon olufokansi ban kigbe mo. Ise fun Krsna niyen. Ti inu Krsna ba ma dun ton ba kigbe mo awon olufokansi ma gba ise na: " Ko buru ma di baba si yin, ma si kigbe mo yin." Ti Krsna bafe ja ikan ninu awon olufokansi re ma di Hiraṇyakaśipu, asi ba ja. Gbogbo awon ise Krsna wa pelu awon olufokansi toni. Nitorina, lati di alabasepo Krsna, lati ni imoye Krsna... Yaśodā-nandana vraja-jana-rañjana. Ise kan soso to ni, ni lati fun awon eyan ni idunnu... bi ise braja-jana ni lati fun Krsna niitelorun, ise Krsna ni lati fun braja-jana ni itelorun. fi ibi sanbi ninu eto ife leleyi. Yamunā-tīra-vana-cārī. Kṛṣṇa, Eledumare, sin rin leti odo Yamuna lati fun awon gopi, awon oluso maalu, awon eye, awon eranko, awon omo maalu ni itelorun. Eye, eranko, ati maalu tab'Okurin lasan kon lonje. Won wa lori ipo to gaju nipa imo arae ni. Kṛta-puṇya-puñjāḥ (SB 10.12.11). Lehin aimoye ibimo lonti de be, lati sere pelu Krsna.

Beena egbe imoye Krsna wa yi si da gan nitporipe gbogob eyan le losi Krsnaloka, ale di albasepo re, tab'ore, tabi orisirisi nkan fun, tabi baba, tabi iya. Krsna asi gba eyikeyi ninu gbogbo awon ipo wanyi. Wanti salaaye awon nkan wanyi ninu iwe Eko Oluwa Caitanya. Beena Krsna o kin kuro ni Vrndavana. Krsna t'alakoko wa ni Vrndavan. Wanti salaaye ninu Brahma samhita,

cintāmaṇi-prakara-sadmasu kalpa-vṛkṣa-
lakṣāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam
lakṣmī-sahasra-śata-sambrahma-sevyamānaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ (tam ahaṁ bhajāmi)
(Bs. 5.29)

Brahmā ti gba Eledumare Govinda, Krsna ninu Vrndavana. Veṇuṁ kvaṇantam: " O sin fon fere."

(veṇuṁ kvaṇantam) aravinda-dalāyatākṣaṁ
barhāvataṁsam asitāmbuda-sundarāṅgam
kandarpa-koṭi-kamanīya-viśeṣa-śobhaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.30)

Beena amu awon iwe wanyi, ati imoye yi, ati prasadam yi nipataki, orin kiko yi, inu yin asi dun, E sii pada si Krsna. Nkan to dara gan leleyi. O daa bayi.