YO/Prabhupada 0435 - We Are Perplexed With These All Worldly Problems



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Olufokansi: " Mio mo bi mosefe mu ibanuje yi kuro ton funmi ni damu. Mio le yo kuro tinba tie ni le yoo kuro tinba tie ni ijoba to lagbara ju laaye yi, pelu agbara bi awon orisa l'orun (BG 2.8) Sanjaya sowipe: Leyin igba to soro bayi tan, Arjuna, eni tole nidari lori awon ota re, sofun Krsna, Govinda, 'Mio ja mo, osi daake (BG 2.9). Iwo toje ebi Bharata, Krsna to wa laarin awon ologun mejeji bere sini rerin, si bere sini salaaye awon oro wanyi si Arjuna (BG 2.10). Olorun to dara si salaaye.."

Prabhupada: Beena taba si mu oro yi nipataki ninu alebu bayi, biwipe ati sonu, sugbon Krsns si rerin siwa. Se ri bayi? Nigbami ale rowipe... Itanraeni leleyi. Apeere kanna, gege bi okurin ton laala, ton kigbe, " Ekun wa nibi, ekun oo. O fe pa mi," Okurin to w ani jiji, bere sini rerin, " Nibo ni ekun na wa? Nibo l'ekun wa?" Okurin na sin kigbe " Ekun, ekun, ekun." Beena, tawa ba tini isoro to po..... Gege bi awon oniselu, nigbami won wa ninu isoro iselu won sin kigbe, "Ile mi leleyi, orile-ede mi leleyi," sugbon apa keji sin kigbe, " Ile mi leleyi, orile-ede mi leleyi," Wan sin ja lojojumo. Krsna rerin. "Kilode ti awon didirin wanyi n'ja nitori ile, ? Wan ja pe ile mi leleyi. Niotooro Krsna loni ile wanyi, awon kan tan ara won je, ninu itanraeni yi, won paariwo, " Ile mi leleyi, Orile-ede mi leleyi," won ti gbagbe fun igba melo lon ma wa lori ile yi. Nkan ton pe ni itanra eni leleyi. Ipo wa leleyi. Laimo nipa ipo wa, asi fun ara wa nidamu lori awon isoro aye yi, eke nigbogbo won je. Janasya moho 'yam ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Itanra-eni nitumo Moha, moha. Itanraeni leleyi. Gbogbo wa lawa labe itanraeni yi. Beena eni toba logbon, toba le ni oye nipa ipo aye yi pe itaraeni loje.... Gbogbo ironu timo ti daale lori awon ofin "Emi" ati "Temi," Itaraeni nigbogbo e je. Beena, teyan ba ti logbon lati jade ninu itanraeni yi, asi teriba fun oluko mimo. Apeere t'Arjuna leleyi. Nigbati idamu yi po fun.. On ba Krsna soro bi ore, sugbon o riwipe " Oro ore s'ore yi kole ranmilowo." Osi mu Krsna bi oluko re nitoripe o mo iyi ti Krsna ni. Oye ko mo na. Ore re loje. Osi mowipe Krsna... "Botilejepe on huwa bi ore simi, sugbon awon olori pataki ti gba pe Olorun fun ara re loje." Nkan t'Arjuna mo leleyi. Beena o sowipe " Idamu yi po gan toje wipe kole yemi mo. Tin ba tie ni isegun ninu ogn yi, inu mi o le dun. taba tie sowipe mo ni'segun lori gbogbo agbaye, ti mo d'Oba gbogbo agbaye tabi ti mo d'orisa l'orun, ibanuje yi kole tan."