YO/Prabhupada 1074 - Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1074 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1073 - Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan|1073|YO/Prabhupada 1075 - Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi|1075}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|0hS8FbIU-cY|All Miseries We Experience in this Material World - It is All Due to This Body - Prabhupāda 1074}}
{{youtube_right|0hS8FbIU-cY|Gbogbo iyan tan je ninu aye yi - nitori ara eda tani - Prabhupāda 1074}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip18.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip18.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Ninu ibo mi ninu Bhagavada-gita wanti salaaye wipe
Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa, Ibomiiran ninu Gita (8.21) o ti wa bayi pe :


:avyakto 'kṣara ity uktas
:avyakto 'kṣara ity uktas
Line 36: Line 39:
:yaṁ prāpya na nivartante
:yaṁ prāpya na nivartante
:tad dhāma paramaṁ mama
:tad dhāma paramaṁ mama
:([[Vanisource:BG 8.21|BG 8.21]])  
:([[Vanisource:BG 8.21 (1972)|BG 8.21]])  


Itumo Avyakta ni oun tio farahan. Beena oni awon apa ile aye yi tawa o le foju ri. Awon iye ara wa o daju to jepe awa o le ri awon irawo to wa, tabi awon isogbe towa ninu agbaye yi. Looto ninu aawon iwe mimo Veda a le ri awon iroyin nipa awon isogbe wanyi. Ale gba tabi rara, sugbon gbogbo awon isogbe wanyi tojepe awa ni asepo pelu, wanti juwe won ninu awoniwe mimo Veda, ninu Srimad-Bhagavtam ni pataki. Sugbon ni odo metalokan, to koja ile aye yi, paras tasmāt tu bhāvo 'nyo ([[Vanisource:BG 8.20|BG 8.20]]), sugbon avyakta yi, toje odo metalokan tio farahan, oun ni paramam gatim, eyan gbodo gbiyanjulati de be. eyan gbodo summo odo metalokan yi, yaṁ prāpya, boya eyan ti de bee tai o fe de bee, na nivartante, eyan o gbodo pada si ile aye yi. Ibe to je odo metalokan Oluwa, lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nisin eyan le beere, bawo lasele losi odo metalokan? Wanti salaay ena ninu Bhagavad-gita. Wanti salaaye ninu apa 8, ese-iwe 5,6,7,8, ilana lati le summo odo metalokan Oluwa won ti salaye nibe pe:  
Avyakta tumọ si lainifarahan Ani ki ise gbogbo isẹda aye ni o wa ni ifihan niwaju wa. Awọn iye ori wa jẹ aláìpé to bẹ ani a ko ti le ri gbogbo awọn irawọ, gbogbo awọn aye ọrun ti wọn wa ninu agbaye yi. A le ri ọpọ alaye gba ninu awọn iwe Vediki nipa gbogbo awọn aye ọrun, a si le gba wọn gbọ tabi ki a ma fiyesi, gbogbo awọn aye ti wọn jẹ pataki, ni wọn ti wa ni apejuwe ninu awọn iwe Vediki, paapa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Sugbon aye ọrun ẹmí, eyi ti o kọja ode aye yi ([[Vanisource:BG 8.20 (1972)|BG 8.20]]), sugbon avyakta yi, eyini alainifarahan, oun ni paramam gatim, O yẹ ki eniyan nifẹ ki o si lepa ijọba ọrun yi, nitori ti a ba de ijọba ọrun na, yaṁ prāpya, ti oluwarẹ ba sunmọ tabi ti o ba de ijọba ọrun na, na nivartante, ko ni si ipada si ile aye yi mọ. eyini ibi ti o jẹ ibugbe ainipekun Oluwa lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nibayi a le se ibeere bawo ni eniyan se le se lati sunmọ ibugbe Oluwa Atobijulọ. Alaye eyi na ti wa ninu Bhagavad-gita. Wọn sọ ni ori iwe kẹjọ, ẹsẹ-iwe 5,6,7,8, ilana lati le sunmọ Oluwa Atobijulọ tabi ibugbe Rẹ na tun ni apejuwe nibẹ. Wọn sọ nibẹ pe:  


:anta-kāle ca mām eva
:anta-kāle ca mām eva
Line 44: Line 47:
:yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ
:yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ
:yāti nāsty atra saṁśayaḥ
:yāti nāsty atra saṁśayaḥ
:([[Vanisource:BG 8.5|BG 8.5]])  
:([[Vanisource:BG 8.5 (1972)|BG 8.5]])  


Anta-kāle, t'aye ba ti pari, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Eni to ba ronu nipa Krsna, smaran, toba le ranti. Eni toba fe ku, lasiko iku, toba le ranti Krsna to fara eda yi sile bo sen ronu, Leyin na o daju pe a pada s'odo metalokan, mad-bhavam. Iwa mimo nitumo Bhavam. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Itumo Mad-bhavam ni gege bi iwa mimo t'Oluwa. gege base juwe tele, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) l'Oluwa. O ni irisi re, sugbon irisi re wa taye raye, sat; o kun fun imoye, cit; ati idunnu, ananda. Nisin awa gan le yee wo fun ara wa boya ara eda tani yi boya sac-cid- ananda loje. Rara. asat l'ara eda yi. Dipo ko je sat, asat loje. Antavanta ime dehā ([[Vanisource:BG 2.18|BG 2.18]]), Bhagavad-gītā sowipe, antavat, fun igba die l'ara eda yi ma wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, odi kedi loje. dipo koje cit, pelu imoye to po, aimokan re lo po. Awa o ni imoye kankan nipa odo metalokan, awa o de ni ogbon gidi kankan nipa ile aye yi. Beena aimoye nkan t'awa o mo, nitorina l'ara eda yi o mo nkankan. Dipo ko logbon, ko mo nkankan. Fun igba die lara eda yi ma wa, ko mo nkankan, ati nirananda. Dipo ko kun fun idunnuj, isoro re po gan. Gbogbo isoro tani ninu aye yi, nitori ara eda yi tani loje.  
Anta-kāle, ni opin aye rẹ, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Ẹnikẹni na, ti o se ìrántí Krsna, smaran, ti o ba le ranti. Eni ti o nku lọ, lasiko iku, ti o ba se ìrántí irisi Krsna ti o ba fi awọ ara rẹ silẹ ninu ero yi, o daju nigbana o ti sunmọ ijọba Ọlọrun., mad-bhavam. Bhavam tumọ si mimọ. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Mad-bhāvam ntọkasi titobi ayanmọ Eledumare. Bi a ti sapejuwe tẹlẹ, Ọba Atobijulọ ni sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) O ni irisi rẹ, irisi rẹ jẹ ainipẹkun, sat; o kún fun ìmọ, cit; ati alaafia, ananda. Nisin awa gan le yẹ wo ti awọ ara wa yi ba jẹ sac-cid-ānanda. Rara. asat ni ara eda yi. Dipo ko jẹ sat, asat lo jẹ. Antavanta ime dehā ([[Vanisource:BG 2.18 (1972)|BG 2.18]]), Bhagavad-gītā sọ wipe, antavat ni ara ẹda yi, fun igba diẹ lo wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, o jẹ asat, ilodi lojẹ. dipo ko jẹ cit, kún fun ìmọ, o kún fun aimọkan. A ko ni imọ ti ijọba ọrun, ani a ko ni imọ ni pipe ti aye yi paapaa. ọpọ awọn nkan wa ti wọn jẹ aimọ si wa, nitorina ara yi jẹ alaimọkan. Dipo ko kún fun ìmọ, o jẹ alaimọkan. Awọ ara wa nsègbé, o kún fun aimọkan, ati nirananda. Dipo ki o kún fun alaafia se ni o kún fun inira. Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:31, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa, Ibomiiran ninu Gita (8.21) o ti wa bayi pe :

avyakto 'kṣara ity uktas
tam āhuḥ paramāṁ gatim
yaṁ prāpya na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 8.21)

Avyakta tumọ si lainifarahan Ani ki ise gbogbo isẹda aye ni o wa ni ifihan niwaju wa. Awọn iye ori wa jẹ aláìpé to bẹ ani a ko ti le ri gbogbo awọn irawọ, gbogbo awọn aye ọrun ti wọn wa ninu agbaye yi. A le ri ọpọ alaye gba ninu awọn iwe Vediki nipa gbogbo awọn aye ọrun, a si le gba wọn gbọ tabi ki a ma fiyesi, gbogbo awọn aye ti wọn jẹ pataki, ni wọn ti wa ni apejuwe ninu awọn iwe Vediki, paapa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Sugbon aye ọrun ẹmí, eyi ti o kọja ode aye yi (BG 8.20), sugbon avyakta yi, eyini alainifarahan, oun ni paramam gatim, O yẹ ki eniyan nifẹ ki o si lepa ijọba ọrun yi, nitori ti a ba de ijọba ọrun na, yaṁ prāpya, ti oluwarẹ ba sunmọ tabi ti o ba de ijọba ọrun na, na nivartante, ko ni si ipada si ile aye yi mọ. eyini ibi ti o jẹ ibugbe ainipekun Oluwa lati be l'awa o ni lati pada wa.. (isinmi) Nibayi a le se ibeere bawo ni eniyan se le se lati sunmọ ibugbe Oluwa Atobijulọ. Alaye eyi na ti wa ninu Bhagavad-gita. Wọn sọ ni ori iwe kẹjọ, ẹsẹ-iwe 5,6,7,8, ilana lati le sunmọ Oluwa Atobijulọ tabi ibugbe Rẹ na tun ni apejuwe nibẹ. Wọn sọ nibẹ pe:

anta-kāle ca mām eva
smaran muktvā kalevaram
yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ
yāti nāsty atra saṁśayaḥ
(BG 8.5)

Anta-kāle, ni opin aye rẹ, lasiko iku. Anta-kāle ca mām eva. Ẹnikẹni na, ti o se ìrántí Krsna, smaran, ti o ba le ranti. Eni ti o nku lọ, lasiko iku, ti o ba se ìrántí irisi Krsna ti o ba fi awọ ara rẹ silẹ ninu ero yi, o daju nigbana o ti sunmọ ijọba Ọlọrun., mad-bhavam. Bhavam tumọ si mimọ. Yaḥ prayāti sa mad-bhāvaṁ yāti. Mad-bhāvam ntọkasi titobi ayanmọ Eledumare. Bi a ti sapejuwe tẹlẹ, Ọba Atobijulọ ni sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) O ni irisi rẹ, irisi rẹ jẹ ainipẹkun, sat; o kún fun ìmọ, cit; ati alaafia, ananda. Nisin awa gan le yẹ wo ti awọ ara wa yi ba jẹ sac-cid-ānanda. Rara. asat ni ara eda yi. Dipo ko jẹ sat, asat lo jẹ. Antavanta ime dehā (BG 2.18), Bhagavad-gītā sọ wipe, antavat ni ara ẹda yi, fun igba diẹ lo wa fun. Ati.. Sac-cid-ananda. Dipo kodi sat, o jẹ asat, ilodi lojẹ. dipo ko jẹ cit, kún fun ìmọ, o kún fun aimọkan. A ko ni imọ ti ijọba ọrun, ani a ko ni imọ ni pipe ti aye yi paapaa. ọpọ awọn nkan wa ti wọn jẹ aimọ si wa, nitorina ara yi jẹ alaimọkan. Dipo ko kún fun ìmọ, o jẹ alaimọkan. Awọ ara wa nsègbé, o kún fun aimọkan, ati nirananda. Dipo ki o kún fun alaafia se ni o kún fun inira. Gbogbo awọn inira ti a ni iriri ni ile aye ni wọn ti inu ara wa.