YO/Prabhupada 1065 - Eyan gbodo ko ni alakoko pe ara eda yi ko loje: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1065 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1064 - Oluwa si wa ninu okan gbogbo awon eda|1064|YO/Prabhupada 1066 - Awon eyan tio logbon won rowipe Otito to Gaju yi pe ko kin seyan|1066}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|e5Bhj0vRsu0|One Has To Learn First Of All That He Is Not This Material Body - Prabhupāda 1065}}
{{youtube_right|e5Bhj0vRsu0|Eyan gbodo ko ni alakoko pe ara eda yi ko loje - Prabhupāda 1065}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660219BG-NEW_YORK_clip09.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660219BG-NEW_YORK_clip09.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Nisin ati bosinu idimu aye yi. Ipo idimu. igberaga wa... imoye eke.. Nitori imoye eke taani lasen rowipe " Lati awon nkan aye yi ni moti jade." Imoye eke niyen. Gbogbo ise wanyi, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke ([[Vanisource:SB 10.84.13|SB 10.84.13]]). Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke, eyan toba wa ninu ironu ara eda yi. Nisin, Oluwa ti salaaye gbogbo Bhagavvad-gita nitoripe Arjuna ti f'ara re si ipo aye yi. Beena eyan gbodo bo lowo ipo aye yi. Ise talakoko wa niyen fun enito bafe bolowo gbogbo awon nkan wanyi. Ni alakoko ogbodo ko wipe ara eda yi ko loje. Taba de ti bo lowo imoye ile aye yi, nkan ton pe ni mukti niyen. Teyan bati bolowo imoye ile aye yi itumo Mukti niyen. Ninu Śrīmad-Bhāgavata isotunmo igbala wa n'be: muktir hitvānyathā rūpaṁ svarūpeṇa vyavasthitiḥ ([[Vanisource:SB 2.10.6|SB 2.10.6]]). Svarūpeṇa vyavasthitiḥ. Igbala lowoo imoye iranu ile aye yi nitumo Mukti, kasi bosinu imoye pipe. gbogbo itosona Bhagavad-gita, wa lati ji imoye yi soke. Awa ma ri ninu apa to keyin ninu itosona lati Bhagavad-gita pe Krsna sin bere lowo Arjuna pe boya imoye re ti yasi mimo. Boya imoye re ti yasi mimo. Lati sise b'Oluwa se fe nitumo imoye mimo yi. Imoye mimo niyen. Koko oro imoye mimo niyen. Imoye yi ti wa nibe, sugbon nitoripe awa si je nkankanna, nitorina losen da wa laamu. O daju pe a le ni isoro lati awon ipo ile aye yi. Sugbon Oluwa Eda to Gaju, kosi bi awon nkan bayi sele dalaamu. Oti koja iru idamu bayi. Iyato laarin Oluwa ati...  
Eniyan gbọdọ kọkọ ni imọ pé oun kọ ni ara ilẹ yi. Nigbati ohun aye ba ti fun wa ni abawọn, a o di mi mọ bi ẹni ide. Ninu ide. Ati igberaga, imoye itanje... Imoye itanjẹ ni ifarahan ninu ero pe emi jẹ isẹ ọwọ ti isẹda aye. Eleyi ni a npe ni itanra ẹni jẹ. Eleyi ni a npe ni itanra ẹni jẹ. Gbogbo akitiyan ile aye, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke ([[Vanisource:SB 10.84.13|SB 10.84.13]]). Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke, ẹni tí ero ara rẹ ti gba lọkan. Nisin, Bhagavad Gita ti jẹ sisọ lọrọ nitoripe Arjuna ti f'ara re si ipo aye yi. Eniyan gbọdọ ni igbala ninu ero ara ti ile aye. Eyini jẹ aṣayan alakọkọ fun awọn oniṣẹ imọlẹ, ti o fẹ ni ominira, ti o fẹ ni igbala. o si gbọdọ kọkọ ni imọ pé oun kọ ni ara ilẹ yi. Imoye yi, tabi imoye ti ile aye... Ni igbati a ba ni igbala ninu imoye aye, iyen ni a npe ni mukti. Mukti, tabi igbala, tumọ si ominira kuro ninu imoye ti aye. Śrīmad-Bhāgavatam na tun funni ni itumọ igbala: muktir hitvānyathā rūpaṁ svarūpeṇa vyavasthitiḥ ([[Vanisource:SB 2.10.6|SB 2.10.6]]). Svarūpeṇa vyavasthitiḥ. Mukti tumọ si ominira kuro ninu imoye eleeri ti ile aye yi, ati ka fi idi mulẹ ninu imoye mimọ. Gbogbo ẹkọ ti inu iwe mimọ Bhagavad-gita ni pinnu lati se isọji imoye mimọ yi, nitori naa a ri ni ipele kẹhin ilana Bhagavad-gītā ti Ọlọrun nbi Arjuna léèrè boya ọkan rẹ ti di mimọ bayi. Boya imoye re ti ni iyasi mimo. Imoye ti o ti ni ya si mimọ tumọ si sise ni ibamu pẹlu awọn ilana ti Oluwa. Eyini ni apapọ gbogbo alaye lori imoye ti o ti ni ya si mimọ. Imoye ti wa nibẹ tẹlẹ nitori a jẹ ẹya ara ti Oluwa, ṣugbọn a ni itẹsi lati jẹki ipa ti o rẹlẹ mu wa lọkan. Itẹsi lati jẹki awon ipo ti aye mu wa lọkan. Ṣugbọn Oluwa, gẹgẹ bi Atobiju, ko si ohun ti nwu lori. Eyi ni iyatọ ti o wa laarin Oluwa Ọlọrun ati awọn olukuluku ẹmi kekeke.  


Kini imoye yi? Imoye eto pe 'Emi ni." Tani mi? Ninu ile aye yi itumo "Emi ni" niwipe " Emi l'olori gbogbo nkan ti mon wo." Imoye idoti niyen. Emi ni "Onigbadun." Gbogbo awon eda ninu aye yi, won rowipe " Emi l'Oluwa ati Eleda gbogbo agbaye yi." Apa meji ni imoye yi ni. Ikan ni wipe "Emi ni Eleda, " Ikeji niwipe " Emi ni onigbadun." Beena Oluwa ni Eleda to daju ati onigbadun to daju. ati awon eda, ton je nkankana pelu Oluwa, eleda tabi onigbadun ko loje, sugbon oni ranlowo loje. Gege bi ero odindin. Awon apa kekere ero na lon fun ero na ni iranlowo. Tabi t'aba keeko nipa bi ara eda se ri. Nisin, ninu ara eda yi, owo wa, ese wa, oju wa, gbogbo awon nkan wanyi lon sise, sugbon apa kekere ara ni gbogbo awon nkan wanyi, awon ko lon gbadun. Ikun lon gbadun. Ese wa sin rin kaakiri Owo wa lon s'ounje, eyin wa lon jeun, ati gbogbo apa ara eda, lon sise lati jeki ikun wa ni itelorun nitoripe ikun wa lo gaju ninu eto ara eda. a gbodo fun ikun wa ni gbogbo nkan. Prāṇopahārāc ca yathendriyāṇām ([[Vanisource:SB 4.31.14|SB 4.31.14]]). Gege bi teyin ba d'omi si gbongbo igi. Tabi ele l'ara to wa laalafia.. Awon apa ara eda - owo, ese, oju, eti, ika owo - gbogbo won lon ma wa laalafia ton ba sise pelu ikun dada. Beena, eda to gajum Oluwa, oun ni onigbadun. Oun ni onigbadun, ati eleda. bi iranlowo si, ni awon eda aye yi je, agbodo sise pelu Re. Ibasepeo yi ma ranwalowo. Fun apeere, teyin ba f'owo bu ounje. Ti ika owo ba bere sini rowipe "kilode toje kin fun ikun ni ounje yi? Eje ka da nikan gbadun e." Asise niyen. Kosi bi ika owo sefe gbadun. Ti ika owo bafe gbadun ijeere ounje na, won gbodo fi ounje na sinu ikun.  
Kini imoye yi? Imoye yi ni "Èmi’’."Kini emi jẹ nígbà náà? Ninu imoye eleeri "Emi " tumọ si "Emi ni Oluwa gbogbo ohun ti o wa ni itọju mi. Imoye eleeri ni yi. Emi ni "Onigbadun." Aye nyi lọ nitori gbogbo ẹda alãye kọọkan ro wipe "Emi ni oluwa ati ẹlẹda ile aye." Imoye aye ni iriran ìpín si meji nipa ti ọkan ati iwa hihu. Ikan ni wipe "Emi ni Eleda, " Ikeji niwipe " Emi ni onigbadun." Sugbọn Ọlọrun Ọba nikan ni awọn mejeeji, Ẹlẹda ati Onigbadun, ati nipa eyi to kan awọn ẹda alãye, gẹgẹ bi ẹya ara Ọlọrun Ọba, wọn ki nse ẹlẹda tabi onigbadun, ṣugbọn alajumọse ni wọn. Fun apẹẹrẹ, ẹya ẹrọ kan se ibasepọ pẹlu gbogbo ẹrọ. Tabi t'i a ba se iwaadi nipa ofin ara wa. Ọwọ, ẹsẹ, oju ati bẹbẹ lọ gbogbo wọn ni awọn ẹya ara, gbogbo awon nkan wonyi ni won nsisẹ, sugbon ni ododo awọn ẹya ara yi kọ ni onigbadun, ikun ni onigbadun. Ese wa sin rin kaakiri Owo wa nse ounje, eyin njeun, ati gbogbo apa ara eda, gbogbo awọn ẹya ara nse isẹ fun itẹlọrun ikun nitori ikun ni opòmulero ti o nsakoso eto ara. Nitorina a fi gbogbo ohun fun ikun. Prāṇopahārāc ca yathendriyāṇām ([[Vanisource:SB 4.31.14|SB 4.31.14]]). A nkẹ igi nipa fifi omi fun gbongbo rẹ. a si nkẹ ara nipa bibọ ikun, Awon apa ara eda - owo, ese, oju, eti, ika owo - gbogbo awọn ẹya ara gbọdọ sowọpọ nitori ki ara ba le wa ni ilera. Bakanna, Ọlọrun Ọba ni onigbadun ati ẹlẹda. ati ni ti wa, bi ẹda alãye to ni tẹriba, ise owo agbara Ọlọrun Ọba, ti wa ni lati sowọpọ fun itẹlọrun Rẹ. Ifọwọsowọpọ yi yio se wa l’anfani. Gẹgẹ bi ounjẹ ti o lọ si inu se jẹ anfani fun gbogbo awọn ẹya ara miiran. Ti awọn ọmọ ika ọwọ ba ro wipe o yẹ ki wọn je ounjẹ fun ara wọn dipo ki wọn fifun ikun Eje ka da nikan gbadun e." Asise niyen. Kosi bi ika owo sefe gbadun. Ti ika owo bafe gbadun ounje na, won gbodo fi ounje na sinu ikun.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 13:11, 21 September 2017



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Eniyan gbọdọ kọkọ ni imọ pé oun kọ ni ara ilẹ yi. Nigbati ohun aye ba ti fun wa ni abawọn, a o di mi mọ bi ẹni ide. Ninu ide. Ati igberaga, imoye itanje... Imoye itanjẹ ni ifarahan ninu ero pe emi jẹ isẹ ọwọ ti isẹda aye. Eleyi ni a npe ni itanra ẹni jẹ. Eleyi ni a npe ni itanra ẹni jẹ. Gbogbo akitiyan ile aye, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13). Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke, ẹni tí ero ara rẹ ti gba lọkan. Nisin, Bhagavad Gita ti jẹ sisọ lọrọ nitoripe Arjuna ti f'ara re si ipo aye yi. Eniyan gbọdọ ni igbala ninu ero ara ti ile aye. Eyini jẹ aṣayan alakọkọ fun awọn oniṣẹ imọlẹ, ti o fẹ ni ominira, ti o fẹ ni igbala. o si gbọdọ kọkọ ni imọ pé oun kọ ni ara ilẹ yi. Imoye yi, tabi imoye ti ile aye... Ni igbati a ba ni igbala ninu imoye aye, iyen ni a npe ni mukti. Mukti, tabi igbala, tumọ si ominira kuro ninu imoye ti aye. Śrīmad-Bhāgavatam na tun funni ni itumọ igbala: muktir hitvānyathā rūpaṁ svarūpeṇa vyavasthitiḥ (SB 2.10.6). Svarūpeṇa vyavasthitiḥ. Mukti tumọ si ominira kuro ninu imoye eleeri ti ile aye yi, ati ka fi idi mulẹ ninu imoye mimọ. Gbogbo ẹkọ ti inu iwe mimọ Bhagavad-gita ni pinnu lati se isọji imoye mimọ yi, nitori naa a ri ni ipele kẹhin ilana Bhagavad-gītā ti Ọlọrun nbi Arjuna léèrè boya ọkan rẹ ti di mimọ bayi. Boya imoye re ti ni iyasi mimo. Imoye ti o ti ni ya si mimọ tumọ si sise ni ibamu pẹlu awọn ilana ti Oluwa. Eyini ni apapọ gbogbo alaye lori imoye ti o ti ni ya si mimọ. Imoye ti wa nibẹ tẹlẹ nitori a jẹ ẹya ara ti Oluwa, ṣugbọn a ni itẹsi lati jẹki ipa ti o rẹlẹ mu wa lọkan. Itẹsi lati jẹki awon ipo ti aye mu wa lọkan. Ṣugbọn Oluwa, gẹgẹ bi Atobiju, ko si ohun ti nwu lori. Eyi ni iyatọ ti o wa laarin Oluwa Ọlọrun ati awọn olukuluku ẹmi kekeke.

Kini imoye yi? Imoye yi ni "Èmi’’."Kini emi jẹ nígbà náà? Ninu imoye eleeri "Emi " tumọ si "Emi ni Oluwa gbogbo ohun ti o wa ni itọju mi. Imoye eleeri ni yi. Emi ni "Onigbadun." Aye nyi lọ nitori gbogbo ẹda alãye kọọkan ro wipe "Emi ni oluwa ati ẹlẹda ile aye." Imoye aye ni iriran ìpín si meji nipa ti ọkan ati iwa hihu. Ikan ni wipe "Emi ni Eleda, " Ikeji niwipe " Emi ni onigbadun." Sugbọn Ọlọrun Ọba nikan ni awọn mejeeji, Ẹlẹda ati Onigbadun, ati nipa eyi to kan awọn ẹda alãye, gẹgẹ bi ẹya ara Ọlọrun Ọba, wọn ki nse ẹlẹda tabi onigbadun, ṣugbọn alajumọse ni wọn. Fun apẹẹrẹ, ẹya ẹrọ kan se ibasepọ pẹlu gbogbo ẹrọ. Tabi t'i a ba se iwaadi nipa ofin ara wa. Ọwọ, ẹsẹ, oju ati bẹbẹ lọ gbogbo wọn ni awọn ẹya ara, gbogbo awon nkan wonyi ni won nsisẹ, sugbon ni ododo awọn ẹya ara yi kọ ni onigbadun, ikun ni onigbadun. Ese wa sin rin kaakiri Owo wa nse ounje, eyin njeun, ati gbogbo apa ara eda, gbogbo awọn ẹya ara nse isẹ fun itẹlọrun ikun nitori ikun ni opòmulero ti o nsakoso eto ara. Nitorina a fi gbogbo ohun fun ikun. Prāṇopahārāc ca yathendriyāṇām (SB 4.31.14). A nkẹ igi nipa fifi omi fun gbongbo rẹ. a si nkẹ ara nipa bibọ ikun, Awon apa ara eda - owo, ese, oju, eti, ika owo - gbogbo awọn ẹya ara gbọdọ sowọpọ nitori ki ara ba le wa ni ilera. Bakanna, Ọlọrun Ọba ni onigbadun ati ẹlẹda. ati ni ti wa, bi ẹda alãye to ni tẹriba, ise owo agbara Ọlọrun Ọba, ti wa ni lati sowọpọ fun itẹlọrun Rẹ. Ifọwọsowọpọ yi yio se wa l’anfani. Gẹgẹ bi ounjẹ ti o lọ si inu se jẹ anfani fun gbogbo awọn ẹya ara miiran. Ti awọn ọmọ ika ọwọ ba ro wipe o yẹ ki wọn je ounjẹ fun ara wọn dipo ki wọn fifun ikun Eje ka da nikan gbadun e." Asise niyen. Kosi bi ika owo sefe gbadun. Ti ika owo bafe gbadun ounje na, won gbodo fi ounje na sinu ikun.