YO/Prabhupada 1071 - T'aba ni asepo pelu Oluwa, ta ba sise fun, lehin na inu wa ma dun: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1071 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1070 - Ise ifarasi Oluwa l'esin tayeraye fun awon eda aye yi|1070|YO/Prabhupada 1072 - Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye tio le paari ninu ijoba towa tayeraye|1072}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|IkcVFxp-K2U|If We Associate with The Lord, Cooperate with Him, Then also We Become Happy - Prabhupāda 1071}}
{{youtube_right|IkcVFxp-K2U|T'aba ni asepo pelu Oluwa, ta ba sise fun, lehin na inu wa ma dun - Prabhupāda 1071}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip15.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip15.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
A le ranti pe taba soro nipa "Krsna" kon se nkan esin. Igbadun to gaju nitumo Oruko Krsna. Wanti jeerisi pe Oluwa ni orisun gbogbo igbadun aye yi. Gbogbo wa lan sa tele igbadun yi. Ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12). Awon eda tab'Oluwa, nitoripe imoye wa po gan, niorina lasen sa tele idunnu. Idunnu. Nigbogbo'gba ni'nu Oluwa dun, taba si ni asepo pel'Oluwa, ta ni asepo pelu re, ta ni asepo pelu Re, lehin na inu wa le dun. Oluwa ti sokale wa sinu ile aye yi lati fi awon akoko idaraya re fi han to kun pelu idunnu. Nigbati Oluwa Sri Krsna wa ni Vrndavana, awon ise re pelu awon oluso maalu omo-okunrin, pelu awon omo-obirin, pelu awon ore re, awon ore obirin, pelu awon olugbe Vrndavana ati ise oluso maalu tonse nigbato kere, gbogbo awon akoko idaraya t'Oluwa Krsna yi kun fun idunnu. Gbogbo Vrndavana, gbogbo awon olugbe Vrndavana, won sa tele. Koseni kankan ninu won to mo afi Krsna. baba Krsna gan o mo, Nigbati Nanda Maharaja fe s'ebo si Indra, nitoripe o si fe salaaye fun awon eyan pe won o gbodo s'adura s'orisa kankan af'Oluwa. Nitoripe ipinnu aye yi ni lati pada s'odo metalokan. Wanti juwe nipa odo metalokan ti Krsna ninu Bhagavad-gita, apa 15, ese-iwe 6,  
Ti a ba ni asepo pelu Oluwa, sowọpọ pẹlu Rẹ, lẹhin na inu wa a dun A le se raniti pe nigba ti a ba darukọ Krishna, ki ise orukọ ẹsin kankan ni a ntọka si. Krishna tumọ si idunnu to ga julọ. O si ni ifọwọlelori pe Oluwa Atobiju ni orisun tabi abà ti gbogbo idunnu. Gbogbo wa ni a nlepa idunnu. Ānanda-Mayo 'bhyāsāt (Vedanta sutra 1.1.12). Awọn ẹda alààyè, bi Oluwa, ni wọn ni ẹkúnrẹrẹ imoye, beni a si nlepa idunnu. Idunnu. Idunnu Oluwa wa titi lailai ti a ba si se asepọ pẹlu Oluwa, se ifọwọsowọpọ pẹlu Rẹ ki a si kopa ninu asepọ Rẹ, nigbana awa na yoo si ni idunnu. Oluwa sọkalẹ sinu aye ikú yi lati fi idaraya rẹ, eyi ti o kún fun ayọ, ni Vrndavana han wa. Nigba ti Oluwa Śrī Kṛṣṇa wà ni Vrndavana, akitiyan rẹ pẹlu awọn ọmọkunrin olusọ-agutan ọrẹ rẹ, pẹlu awọn ọrẹ rẹ ọmọbinrin, pẹlu awọn olugbe miiran ni Vrndavana ati pẹlu awọn malu gbogbo wọn ni wọn kún fun ayọ. Gbogbo awọn araalu Vrndavana lapapọ wọn nse ilepa Re wọn o mọ nkankan ju Krishna lọ. Ṣugbọn ani Oluwa Ọlọrun mu ọkan baba rẹ Nanda Maharaja kuro ninu isìn orisa Indra, nitori o fẹ fi ni idi mulẹ daju wipe awọn eniyan o nilo lati sin eyikeyi orisa akunlẹbọ. Oluwa Atobiju nikan ni o to sin, nitori ìlépa wọn nigbẹhin ni lati pada si ibugbe Rẹ. Ibugbe Oluwa Śrī Kṛṣṇa ni sapejuwe ninu Bhagavad Gita, ori iwe Kẹdogun, ẹsẹ kẹfa:


:na tad bhāsayate sūryo
:na tad bhāsayate sūryo
Line 36: Line 39:
:yad gatvā na nivartante
:yad gatvā na nivartante
:tad dhāma paramaṁ mama
:tad dhāma paramaṁ mama
:([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]).
:([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]])


Nisin alaaye nipa sanmo yi to wa tayeraye.. T'aba n'soro nipa sanmo, nitoripe awa ti baramu pelu sanmo lasan, nitorina a ma bere sini ronu nipa orun, osupa, erawo, at bayi lo. Sugbon Oluwa sowipe ni sanmo tayeraye yi, orun o wulo. Na tad bhāsayate sūryo na śaśāṅko na pāvakaḥ ([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]). Kode si'wulo fun osupa. Itumo Na pāvakaḥ niwipe kosi'wulo fun ina monamkna tani ina lati tanna nitoripe sanmo mimo yi, tin tanna fun ara re lati brahma-jyotir. Brahmajyoti, yasya prabhā (BS 5.40), ina lati odo metalokan. Nison lasiko tawayi, ti awon eyan fe losi awon isogbe imi, Kole lati ni oye nipa odo metalokan t'Oluwa. Odo metalokan t'Ouwa wa ninu sanmo mimo, Goloka l'oruko re je. Ninu Brahma-samhita wanti salaaye dada, goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (BS 5.37). Botilejepe Oluwa wa ni odo metalokan re, Goloka, beena akhilātma-bhūtaḥ loje, e le ni asepo pelu re lati bi na. nitorina ni Oluwa sen wa lati fi ara re han, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1), bayi koni sejo pe awa fe f'oju inu wo. Kosejo irori.  
Ẹsẹ yìí funni ni apejuwe ti ọrun alakeji... Dajudaju ero aye wa ni a fi npe ọrun, a si nro ni itanmọ pẹlu oorun, osupa, irawọ ati bẹ bẹ lọ, Sugbon Oluwa sowipe ni sanmo tayeraye yi, orun o wulo. Na tad bhāsayate sūryo na śaśāṅko na pāvakaḥ ([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]]). sugbọn ko si ilo nibẹ fun oṣupa. Itumo Na pāvakaḥ niwipe kosi'wulo fun ina monamkna tani ina lati tanna nitori ọrun ẹmi ti ni itana tẹlẹ nipasẹ Brahma-jyotir, Brahmajyoti, yasya prabhā (BS 5.40), imọlẹ ti o nti ọdọ Oluwa Atobiju wa. Nisinyi lasiko ti awayi, ti awon eniyan ntiraka lati de aye ọrun miiran, sugbọn ko soro lati ni oye ibugbe ti Oluwa Atobiju. Eyini ni Ibugbe ti o ni tọka si bi Goloka, ni isalu ọrun. Apejuwe rẹ ti wa ni ẹwà ninu Brahma-samhita, goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (BS 5.37). Bi otilẹjẹpe, Oluwa ngbe titi ayeraye ninu ibugbe Rẹ Goloka, sibẹ O jẹ akhilātma-bhūtaḥ, O ti see sumọn lati aiye yi, ati fun ipa yi Oluwa nwa lati fi ara rẹ gidi han, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) Nigbati O ba fi ẹya yi han, ko si idi fun wa lati ma gbiro nkan ti O jọmọ.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:30, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Ti a ba ni asepo pelu Oluwa, sowọpọ pẹlu Rẹ, lẹhin na inu wa a dun A le se raniti pe nigba ti a ba darukọ Krishna, ki ise orukọ ẹsin kankan ni a ntọka si. Krishna tumọ si idunnu to ga julọ. O si ni ifọwọlelori pe Oluwa Atobiju ni orisun tabi abà ti gbogbo idunnu. Gbogbo wa ni a nlepa idunnu. Ānanda-Mayo 'bhyāsāt (Vedanta sutra 1.1.12). Awọn ẹda alààyè, bi Oluwa, ni wọn ni ẹkúnrẹrẹ imoye, beni a si nlepa idunnu. Idunnu. Idunnu Oluwa wa titi lailai ti a ba si se asepọ pẹlu Oluwa, se ifọwọsowọpọ pẹlu Rẹ ki a si kopa ninu asepọ Rẹ, nigbana awa na yoo si ni idunnu. Oluwa sọkalẹ sinu aye ikú yi lati fi idaraya rẹ, eyi ti o kún fun ayọ, ni Vrndavana han wa. Nigba ti Oluwa Śrī Kṛṣṇa wà ni Vrndavana, akitiyan rẹ pẹlu awọn ọmọkunrin olusọ-agutan ọrẹ rẹ, pẹlu awọn ọrẹ rẹ ọmọbinrin, pẹlu awọn olugbe miiran ni Vrndavana ati pẹlu awọn malu gbogbo wọn ni wọn kún fun ayọ. Gbogbo awọn araalu Vrndavana lapapọ wọn nse ilepa Re wọn o mọ nkankan ju Krishna lọ. Ṣugbọn ani Oluwa Ọlọrun mu ọkan baba rẹ Nanda Maharaja kuro ninu isìn orisa Indra, nitori o fẹ fi ni idi mulẹ daju wipe awọn eniyan o nilo lati sin eyikeyi orisa akunlẹbọ. Oluwa Atobiju nikan ni o to sin, nitori ìlépa wọn nigbẹhin ni lati pada si ibugbe Rẹ. Ibugbe Oluwa Śrī Kṛṣṇa ni sapejuwe ninu Bhagavad Gita, ori iwe Kẹdogun, ẹsẹ kẹfa:

na tad bhāsayate sūryo
na śaśāṅko na pāvakaḥ
yad gatvā na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 15.6)

Ẹsẹ yìí funni ni apejuwe ti ọrun alakeji... Dajudaju ero aye wa ni a fi npe ọrun, a si nro ni itanmọ pẹlu oorun, osupa, irawọ ati bẹ bẹ lọ, Sugbon Oluwa sowipe ni sanmo tayeraye yi, orun o wulo. Na tad bhāsayate sūryo na śaśāṅko na pāvakaḥ (BG 15.6). sugbọn ko si ilo nibẹ fun oṣupa. Itumo Na pāvakaḥ niwipe kosi'wulo fun ina monamkna tani ina lati tanna nitori ọrun ẹmi ti ni itana tẹlẹ nipasẹ Brahma-jyotir, Brahmajyoti, yasya prabhā (BS 5.40), imọlẹ ti o nti ọdọ Oluwa Atobiju wa. Nisinyi lasiko ti awayi, ti awon eniyan ntiraka lati de aye ọrun miiran, sugbọn ko soro lati ni oye ibugbe ti Oluwa Atobiju. Eyini ni Ibugbe ti o ni tọka si bi Goloka, ni isalu ọrun. Apejuwe rẹ ti wa ni ẹwà ninu Brahma-samhita, goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (BS 5.37). Bi otilẹjẹpe, Oluwa ngbe titi ayeraye ninu ibugbe Rẹ Goloka, sibẹ O jẹ akhilātma-bhūtaḥ, O ti see sumọn lati aiye yi, ati fun ipa yi Oluwa nwa lati fi ara rẹ gidi han, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1) Nigbati O ba fi ẹya yi han, ko si idi fun wa lati ma gbiro nkan ti O jọmọ.