YO/Prabhupada 1072 - Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye tio le paari ninu ijoba towa tayeraye: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1072 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1071 - T'aba ni asepo pelu Oluwa, ta ba sise fun, lehin na inu wa ma dun|1071|YO/Prabhupada 1073 - Beena botilejepe awa o le ye ironu lati d'oga iseda aye yi kuro l'okan|1073}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|4qABEkWNbuQ|Leaving this Material World and get our Eternal Life in the Eternal Kingdom - Prabhupāda 1072}}
{{youtube_right|4qABEkWNbuQ|Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye tio le paari ninu ijoba towa tayeraye<br />- Prabhupāda 1072}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip16.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip16.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Oluwa ti funwa l'ore ofe re ninu ara re Śyāmasundara-rūpa. Sugbon awon eyan tio logbon sin foju kekere wo. Avajānanti māṁ mūḍhā ([[Vanisource:BG 9.11|BG 9.11]]). Nitoripe Oluwa ti wa bi ikan ninu wa, ton sere pelu fere bi eda eyan, nitorina awa o gbodo rowipe ikan ninu wa l'Olorun je. Pelu agbara re lati wa nibiki toba fe lose wa niwaju pelu ara re to si fi awon akoko idaraya re fi han, lati le nipa odo metalokan re. Beena odo metalokan Oluwa, aimoye awon isogbe na to wa ninu brahma-jyotir yi. gege b'ase ni aimoye awon isogbe ton fo kaa kiri lori ina orun, beena, ninu brahma-jyotir, ton jade kuro ninu odo metalokan Oluwa, Krsnaloka, Goloka, ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhis (BS 5.37), mimo ni gbogbo awon isogbe wanyi. ānanda-cinmaya ni won; awon isogbe lasan ko lon je. Beena Oluwa ti sowipe,  
Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye ainipẹkun ni ijọba ọrun. Oluwa si fi ara Rẹ han nipa ore-ọfẹ Rẹ, bi o ti wa, gẹgẹ bi Śyāmasundara-rūpa. Osenilaànu, pe awọn alaimoye se ni yẹpẹrẹ Avajānanti māṁ mūḍhā ([[Vanisource:BG 9.11 (1972)|BG 9.11]]). Nitori ti o ti wa ninu awọ ara eniyan ti o si nsere pẹlu wa bi ọkan ninu wa, Ṣugbọn a ko le titori eyi daro Oluwa bi ọkan ninu wa. O jẹ nipa agbara Rẹ ti o fi ara rẹ gidi han niwaju wa ati ti o si fi idaraya rẹ han, eyi ti wọn jọra mọ awọn idaraya ninu ibugbe Rẹ.. Awọn aye ainiye ni wọn leefo ninu itansan imọlẹ, eyini brahma-jyotir. gege b'ase ni aimoye awon isogbe ti wọn leefo ninu itansan imọlẹ oorun, bee na, ninu brahma-jyotir, ti o jade lati inu ibugbe to ga julọ, Kṛṣṇaloka, Goloka, ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhis (BS 5.37), mimọ ni gbogbo awọn isọgbe wọnyi. ānanda-maya, awọn aye cin-maya, ti wọn kii se ti aye ilẹ Bee na Oluwa sọ wipe, na tad


:na tad bhāsayate sūryo
:na tad bhāsayate sūryo
Line 36: Line 39:
:yad gatvā na nivartante
:yad gatvā na nivartante
:tad dhāma paramaṁ mama
:tad dhāma paramaṁ mama
:([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]])  
:([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]])  


Nisin enikeni tole summo sanmo mimo yi koni pada si sanmo ile aye yi. Toje pe awa si wa ninu ile aye yi, kama wa soro nipa isogbe osupa... Isogbe osupa, lo summo wa ju, sugbon taba tie de isogbe to gaju yi, ton pe ni Brahmaloka, nibe, awon isoro aye yina wa, Mon soro nipa ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan. Kosi isogbe aye yi tio awon isoro merin wanyi o si mo. Nitorina Oluwa ti soro ninu Bhagavad-gita wipe, ābrahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna ([[Vanisource:BG 8.16|BG 8.16]]). Awon eda aye yi tonse irin ajo lati isogbe kan sikeji. konsepe da dede losi awon isogbe imi pelu awon ero sputnik. Enikeni toba fe losi awon isogbe imi, ilana toma tele wa. Yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ ([[Vanisource:BG 9.25|BG 9.25]]). Teyan bafe losi awon isogbe imi bi osupa, awa o gbodo lo sputnik lati de bee. Bhagavad-gita ti salaaye wipe, yānti deva-vratā devān. Awon isogbe osupa tabi isogbe orun tabi awon isogbe lori Bhūloka, tonpe ni Svargaloka. Svargaloka. Bhūloka, Bhuvarloka, Svargaloka. Awon isogbe pelu ipo orisirisi leleyi. Beena Devaloka, bonse mo won niyen. Bhagavad-gita ti funwa ni itosona to rorun pe teyin ba fe lopsio awon isogbe giga wanyi, Devaloka. Yānti deva-vratā devān. Yānti deva-vratā devān. Deva-vratā, taba se adase lori eto ebo si awon orisa to wa lori isogbe yi, lehin na a le losi isogbe tafe. A le losi isogbe orun gan, isogbe osupa, ale losi awon isogbe orun, sugbon Bhagavad-gita o fe ka losi awon isogbe wanyi ton wa niu ile aye yi, nitoripe taba tie losi Brahmaloka, isogbe to gaju, ti awon onisayensi ti siro pe lati de bee pelu awon sputnik wanyi o ma to odun 40,000. Nisin kosi basele gbe laye yi to odun 40,000 lati de isogbe to gaju yi ninu ile aye yi. Sugbon teyan ba fi ile aye re fi s'adura s'orisa to wa lori isogbe yi, o le losi be, bon se juwe ninu Bhagavad-gītā: yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ ([[Vanisource:BG 9.25|BG 9.25]]). Beena, Pitrloka leleyi. Beena, enikeni toba fe losi isogbe to gaju... Krsnaloka loje isogbe to gaju. Ninu sanmo mimo yi, aimoye awon isogbe to wa nibew, awon isogbe sanatana, awon isogbe tayeraye, tio le paare. Sugbon ninu gbogbo awon isogbe mimo wanyi, o ni'kan, t'alakoko, ton pe ni Goloka Vrndavana. Beena awon iroyion wanyi wa ninu Bhagavad-gita, a de ti gba'aye lati jade kuro ninu ile aye yi, kasi gba ile aye towa tayeraye ninu odo metalokan tayeraye.  
Ẹni ti o ba le sunmọ ọrun ẹmí yi ko ni lati sọkale mọ si ode aye. Ninu ode aye, ki a ma wa sọ nipa ti oṣupa... Isogbe osupa, lo summo wa ju, sugbon taba tie de isogbe to gaju yi, ani ti a ba tilẹ sunmọ aye to ga julọ (Brahmaloka), a ma ri awọn inira inu aye kanna, eyun inira ibimọ, iku, aisan ati arugbo. Ko si aye kan ni gbogbo agbaye ti o ni iyọkuro ninu awọn ipinlẹ mẹrin ti igbesi aye wọnyi. Nitorina Oluwa si sọ ninu Bhagavad-gita wipe, ābrahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna ([[Vanisource:BG 8.16 (1972)|BG 8.16]]). Awọn ẹda alààyè ti nrin irin ajo lati aye kan si miran, sugbọn ki se pe a le lọ si aye eyikeyi ti a fẹ nipa eto ohun elo. Ti a ba fẹ lati lọ si aye ọrun miiran, ilana wa bi a se nlọ sibẹ. Yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ ([[Vanisource:BG 9.25 (1972)|BG 9.25]]). Ti a ba fẹ lati lọ si aye ọrun miiran, ka so wipe, oṣupa, , awa o gbodo gbiyanju lati lọ nipa eto ohun elo. Bhagavad-gita ti salaaye wipe, yānti deva-vratā devān. Oṣupa, oorun ati awọn aye ọrun ti wọn ga ni a npe ni Svargaloka. Svargaloka. Bhūloka, Bhuvarloka, Svargaloka. Awon orisi ipo aye ti o yatọ ni wọn wa nbe. Beena Devaloka, bonse mo won niyen. Bhagavad Gita kọ wa bi a se le se irin ajo lọ si awọn ọna aye ti o ga (Devaloka) pẹlu afise ti o rọrun pupọ. Yānti deva-vratā devān. Yānti deva-vratā devān. Deva-vratā, Ẹ kan lati sin awọn orisa akunlẹbọ pataki ti aye na, lehin na a le losi isogbe tafe. A le lọ si ori oṣupa, oorun tabi eyikeyi ninu awọn ọna aye ti o ga. Sibẹsibẹ Bhagavad Gita ko da ni nimọran lati lọ si eyikeyi ninu awọn isalu aye yi, nitori ani ti a ba lọ si Brahmaloka, aye ti o ga julọ, ti awon onisayensi ti siro pe lati de bee nipasẹ awọn ohun elo ẹrọ kan nipa boya ririn fun ọkẹ ọdun tani o si le gbe le aye fun iye igba na lati lo si aye ọrun ti o ga julọ? Sugbon ti eyan ba fi aye rẹ sin orisa-akunlẹbọ ti aye ọrun kan pato, o le lọ si bẹ, Bhagavad-gītā se ni imọran: yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ ([[Vanisource:BG 9.25 (1972)|BG 9.25]]). Bakanna, Pitrloka na wa. Ṣugbọn ẹni ti o ba fẹ lati sunmọ aye ọrun ti o ga julọ, Aye ọrun ti o ga julọ ni Kṛṣṇaloka. Ninu isalu ọrun yi, aimoye ọrun alakeji ni wọn wa nibe, awọn ọrun sanatana, awọn ọrun ayeraye, ti wọn ko ni iparun. Sugbon ninu gbogbo awọn aye ti ẹmí ọrun wọnyi ẹyọkan wa aye atetekọse ti a npe ni Goloka Vrndavana. Gbogbo awọn ẹkọ yi ni Bhagavad Gita ti fun ni, a si tun gba nipasẹ awọn imọran rẹ ẹkọ bi a se le fi ile aye silẹ lati bẹrẹ aye alayọ gidi gan ninu ijọba ọrun.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:30, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Ka fi ile aye yi sile ka pada s'aye ainipẹkun ni ijọba ọrun. Oluwa si fi ara Rẹ han nipa ore-ọfẹ Rẹ, bi o ti wa, gẹgẹ bi Śyāmasundara-rūpa. Osenilaànu, pe awọn alaimoye se ni yẹpẹrẹ Avajānanti māṁ mūḍhā (BG 9.11). Nitori ti o ti wa ninu awọ ara eniyan ti o si nsere pẹlu wa bi ọkan ninu wa, Ṣugbọn a ko le titori eyi daro Oluwa bi ọkan ninu wa. O jẹ nipa agbara Rẹ ti o fi ara rẹ gidi han niwaju wa ati ti o si fi idaraya rẹ han, eyi ti wọn jọra mọ awọn idaraya ninu ibugbe Rẹ.. Awọn aye ainiye ni wọn leefo ninu itansan imọlẹ, eyini brahma-jyotir. gege b'ase ni aimoye awon isogbe ti wọn leefo ninu itansan imọlẹ oorun, bee na, ninu brahma-jyotir, ti o jade lati inu ibugbe to ga julọ, Kṛṣṇaloka, Goloka, ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhis (BS 5.37), mimọ ni gbogbo awọn isọgbe wọnyi. ānanda-maya, awọn aye cin-maya, ti wọn kii se ti aye ilẹ Bee na Oluwa sọ wipe, na tad

na tad bhāsayate sūryo
na śaśāṅko na pāvakaḥ
yad gatvā na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 15.6)

Ẹni ti o ba le sunmọ ọrun ẹmí yi ko ni lati sọkale mọ si ode aye. Ninu ode aye, ki a ma wa sọ nipa ti oṣupa... Isogbe osupa, lo summo wa ju, sugbon taba tie de isogbe to gaju yi, ani ti a ba tilẹ sunmọ aye to ga julọ (Brahmaloka), a ma ri awọn inira inu aye kanna, eyun inira ibimọ, iku, aisan ati arugbo. Ko si aye kan ni gbogbo agbaye ti o ni iyọkuro ninu awọn ipinlẹ mẹrin ti igbesi aye wọnyi. Nitorina Oluwa si sọ ninu Bhagavad-gita wipe, ābrahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna (BG 8.16). Awọn ẹda alààyè ti nrin irin ajo lati aye kan si miran, sugbọn ki se pe a le lọ si aye eyikeyi ti a fẹ nipa eto ohun elo. Ti a ba fẹ lati lọ si aye ọrun miiran, ilana wa bi a se nlọ sibẹ. Yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ (BG 9.25). Ti a ba fẹ lati lọ si aye ọrun miiran, ka so wipe, oṣupa, , awa o gbodo gbiyanju lati lọ nipa eto ohun elo. Bhagavad-gita ti salaaye wipe, yānti deva-vratā devān. Oṣupa, oorun ati awọn aye ọrun ti wọn ga ni a npe ni Svargaloka. Svargaloka. Bhūloka, Bhuvarloka, Svargaloka. Awon orisi ipo aye ti o yatọ ni wọn wa nbe. Beena Devaloka, bonse mo won niyen. Bhagavad Gita kọ wa bi a se le se irin ajo lọ si awọn ọna aye ti o ga (Devaloka) pẹlu afise ti o rọrun pupọ. Yānti deva-vratā devān. Yānti deva-vratā devān. Deva-vratā, Ẹ kan lati sin awọn orisa akunlẹbọ pataki ti aye na, lehin na a le losi isogbe tafe. A le lọ si ori oṣupa, oorun tabi eyikeyi ninu awọn ọna aye ti o ga. Sibẹsibẹ Bhagavad Gita ko da ni nimọran lati lọ si eyikeyi ninu awọn isalu aye yi, nitori ani ti a ba lọ si Brahmaloka, aye ti o ga julọ, ti awon onisayensi ti siro pe lati de bee nipasẹ awọn ohun elo ẹrọ kan nipa boya ririn fun ọkẹ ọdun tani o si le gbe le aye fun iye igba na lati lo si aye ọrun ti o ga julọ? Sugbon ti eyan ba fi aye rẹ sin orisa-akunlẹbọ ti aye ọrun kan pato, o le lọ si bẹ, Bhagavad-gītā se ni imọran: yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ (BG 9.25). Bakanna, Pitrloka na wa. Ṣugbọn ẹni ti o ba fẹ lati sunmọ aye ọrun ti o ga julọ, Aye ọrun ti o ga julọ ni Kṛṣṇaloka. Ninu isalu ọrun yi, aimoye ọrun alakeji ni wọn wa nibe, awọn ọrun sanatana, awọn ọrun ayeraye, ti wọn ko ni iparun. Sugbon ninu gbogbo awọn aye ti ẹmí ọrun wọnyi ẹyọkan wa aye atetekọse ti a npe ni Goloka Vrndavana. Gbogbo awọn ẹkọ yi ni Bhagavad Gita ti fun ni, a si tun gba nipasẹ awọn imọran rẹ ẹkọ bi a se le fi ile aye silẹ lati bẹrẹ aye alayọ gidi gan ninu ijọba ọrun.