YO/Prabhupada 1076 - lasiko iku ale wa nibi, tabi ka pada si odo metalokan: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 1: Line 1:
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN CATEGORY LIST -->
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0001 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 1076 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - 1966]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1075 - Awa sin seto ile aye wa to kan ninu aye yi|1075|YO/Prabhupada 1077 - Oluwa tosi wa ni pipe, kosi iyato kankan laarin Oruko re at'Oun fun ara re|1077}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|C--XKEnj9pA|At the Time of Death We Can Remain Here, or Transfer Into the Spiritual World - Prabhupāda 1076}}
{{youtube_right|C--XKEnj9pA|Lasiko iku ale wa nibi, tabi ka pada si odo metalokan - Prabhupāda 1076}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660220BG-NEW_YORK_clip20.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660220BG-NEW_YORK_clip20.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
bhāva orisirisi lowa. Nisin, ikan ninu awon bhava ni iseda aye yi, ati salaaye tele, pe ifihan ikan ninu awon agbara Eledumare ni ile aye yi je. Ninu Visnu Purana, won ti juwe gbogob agbara Eledumare nibe.
Lasiko iku a le duro nibi, tabi ka pada si ijọba Ọlọrun. bhava orisirisi lo wa. Nisin, iseda aye yi na je ọkan ninu awọn bhavas ni, bi ati salaaye tele, wipe isẹda aye jẹ asehan ọkan ninu awọn okunagbara ti Ọlọrun Ọba. Ninu Viṣṇu Purāṇa apapọ okunagbara Ọlọrun Ọba ti wa ni ijuwe:


:viṣṇu-śaktiḥ parā proktā
:viṣṇu-śaktiḥ parā proktā
Line 38: Line 41:
:([[Vanisource:CC Madhya 6.154|CC Madhya 6.154]])  
:([[Vanisource:CC Madhya 6.154|CC Madhya 6.154]])  


Gbogbo awon agbara, Parāsya śaktir vividhaiva śrūyate ([[Vanisource:CC Madhya 13.65|CC Madhya 13.65, purport]]). Orisirisi agbara l'Oluwa ni, aimoye agbara tio le ye wa. Sugbon awon alakowe, awon eda miko won ti sewaadi won de ti salaaye gbogbo agbara wanyi pin s'ona meta. Ikini.. gbogbo awon agbara wanyi viṣṇu-śakti ni won. Lati agbara orisirisi ti Visnu ni awon agbara wanyi. Nisin, para ni agbara yi, to gaju. Ati kṣetra-jñākhyā tathā parā, ati awon eda, kṣetra-jña, awon na wa ninu apa agabra giga yi, wanti jeerisi ninu Bhagavad-gita na. Ati salaaye tele. Awon agabra iyoku, agbara ile aye yi, ṛtīyā karma-saṁjñānyā ([[Vanisource:CC Madhya 6.154|CC Madhya 6.154]]). Agbara to ku wa ninu ipo aimokan. Beena agbara ile aye yi niyen. Beena bhagavd ni agbara ile aye yi na - ( ko daju). Beena lasiko iku, boya ka wa pelu agbara ile aye yi, tabi ile aye yi, tabi ka pada si odo metalokan. awon oan to wa niyen. Beena Bhagavad-gita sowipe,
Gbogbo awon agbara, Parāsya śaktir vividhaiva śrūyate ([[Vanisource:CC Madhya 13.65|CC Madhya 13.65, purport]]). Ọlọrun Ọba ni oniruuru ati ainiye okunagbara eyi ti o kọja ero wa. sibẹsibẹ, awọn ọjọgbọn akẹkọ nla tabi awọn ẹmi ti wọn ti ni igbala ninu ẹsẹ ti se iwadi si ti se akopọ gbogbo awọn okunagbara wọnyi si ọna mẹta, Ikini ni pe... gbogbo awọn okunagbara na ni wọn jẹ Viṣṇu-śakti. gbogbo awọn okunagbara, wọn jẹ awọn orisi agbara ti Oluwa Viṣṇu. Nisin, para ni agbara yi, to gaju. Ati kṣetra-jñākhyā tathā parā, ati awon eda, kṣetra-jña, awọn ẹda alaaye na tun jẹ agbara to ga wanti jeerisi ninu Bhagavad-gita na. A ti salaaye tẹlẹ. Awon agabra iyoku, agbara ile aye yi, ṛtīyā karma-saṁjñānyā ([[Vanisource:CC Madhya 6.154|CC Madhya 6.154]]). Awọn okunagbara miiran, wọn jẹ ti ipo aimọkan. Bẹ eyinni jẹ okunagbara aye. Bẹ okunagbara aye na - ( ko daju). Ni akoko ti iku ba de a le duro boya ninu agbara ti o rẹlẹ ti aye yi, tabi ile aye yi, tabi ki a ni igbe lọ sinu agbara ti awọn aye ọrun. Eyinni jẹ bosewa. Bẹ ni Bhagavad Gita sọ pé: yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ tyajaty ante kalevaram taṁ tam evaiti kaunteya sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ


:yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
:yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
Line 44: Line 47:
:taṁ tam evaiti kaunteya
:taṁ tam evaiti kaunteya
:sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
:sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
:([[Vanisource:BG 8.6|BG 8.6]])  
:([[Vanisource:BG 8.6 (1972)|BG 8.6]]) .


Nisin, bose ti mowa lara latii ronu, nipa agbara aye yi tabi agbara mimo, nisin, bawo lasele lo ironu yi? Ironu ile aye yi, basele le yi pada sii ironu nipa agbara mimo? Beena fun ironu nipa agabra mimo awon iwe mimo Veda wa nibe. Beena lati ronu nipa awon agbara ile aye yi, awon iwe aye yi po gan - iwe iroyin, iwe itan, ati bayi bayi lo. O kun fun iwe. Beena ironu wa, ti wole sinu awon iwe wanyi. Beena, taba fe yi ironu wa s'ona mimo, lehin na agbodo bere sini ka awon iwe mimo Veda. Nitorina awon alakowe ti ko awon iwe mimo Veda to po gan, awon Purana. Itan lasan ko ni awon Purana. Awon itan akoole niyen. Ninu Caitanya-caritamrta oni awon ese iwe ton salaaye bayi. Anādi-bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli' gela ataeva kṛṣṇa veda-purāṇa kailā ([[Vanisource:CC Madhya 20.117|CC Madhya 20.117]]). Pe awon edfa aye yi, won ti gbagbe nipa asepo ton ni pely Eledumare, won ronu nipa awon ise ile aye yi. lati yi agbara ironu awon eyan wanyi si awon nkan mimo, Kṛṣṇa-dvaipāyana Vyāsa, ti ko awon iwe mimo to po gan. Itumo iwe mimo Veda niwipe, ni alakoko o pin awon iwe yi si merin. Lehin na o salaaye lori won pelu awon Purana. Fun awon eyan tio le ye bi awon strī, śūdra, vaiśya, o ko iwe Mahābhārata. Ninu Mahabharata o si juwe nipa Bhagavad-gita. Lehin na otun fun wa ni sonisoki nipa iwe Veda ninu Vedanta-sutra. Ati Vedantr-sutra lati le funwa ni itonisona loo jowaju, o de funwa ni Srimad-Bhagavatam to salaaye fun ara re.  
Bayi a nsaba lero si, boya agbara aye tabi agbara ẹmi. Bayi, bawo ni a se le dari ero na? Ironu ile aye bawo ni a se le gbe ero wa lati inu agbara aye si agbara ẹmí? Bẹ na fun eronu nipa agbara mimo awọn iwe ilana Vediki wa nibẹ. Gẹgẹ bi ọpọlọpọ awọn iwe ni wọn wa fun ero ti agbara aye iwe iroyin, akọọlẹ, iwe, bẹ bẹ lọ. O kun fun iwe. Bẹ ni wọn fi ọkan wa kun fun ero ninu awọn iwe wọnyi. Bakanna, ti a ba fẹ gbe ero wa sinu agbara ẹmí, nigbana a gbọdọ rọpo wọn pẹlu awọn iwe Vediki. Nitorina, awọn ọjọgbọn nla ti kọ ọpọlọpọ awọn iwe ilana Vediki, Awọn Purāṇas ko wa lati inu igbiro; wọn jẹ awọn itan igbasilẹ. Ninu Caitanya-caritamrta ese iwe kan salaaye bayi. Anādi-bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli' gela ataeva kṛṣṇa veda-purāṇa kailā ([[Vanisource:CC Madhya 20.117|CC Madhya 20.117]]). Awọn eda alãye ti wọn ni igbagbe tabi ti wọn wa ninu idé yi, wọn ti gbagbe ibasepọ wọn pẹlu Ọlọrun Ọba, ti ero awọn akitiyan aye si ti gba wọn l’ọkan. Ani ki wọn kan fi le gbe agbara iro wọn si sàkaani ọrun, Krsna-dvaipāyana Vyāsa ti fi iye ojulowo iwe ilana Vediki silẹ. Ni akọkọ o pín awọn Vedas si mẹrin. Lẹhinna o si salaye wọn ninu awọn Purāṇas. Ati fun awọn eniyan ti wọn ko l’oye pupọ bi awọn strī, śūdra, vaiśya o ti kọ Mahābhārata, O si funni ni Bhagavad Gita ninu Mahābhārata. Lẹhin na o tun fun wa ni akopọ gbogbo ilana Vediki ni soki ninu Vedanta sutra. ati fun itọnisọna l’ọjọ iwaju lori Vedanta sutra, o se àsọyé tinu-tinu ti a npe ni Śrīmad-Bhāgavatam funrarẹ.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:31, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Lasiko iku a le duro nibi, tabi ka pada si ijọba Ọlọrun. bhava orisirisi lo wa. Nisin, iseda aye yi na je ọkan ninu awọn bhavas ni, bi ati salaaye tele, wipe isẹda aye jẹ asehan ọkan ninu awọn okunagbara ti Ọlọrun Ọba. Ninu Viṣṇu Purāṇa apapọ okunagbara Ọlọrun Ọba ti wa ni ijuwe:

viṣṇu-śaktiḥ parā proktā
kṣetra-jñākhyā tathā par
avidyā-karma-saṁjñānyā
tṛtīyā śaktir iṣyate
(CC Madhya 6.154)

Gbogbo awon agbara, Parāsya śaktir vividhaiva śrūyate (CC Madhya 13.65, purport). Ọlọrun Ọba ni oniruuru ati ainiye okunagbara eyi ti o kọja ero wa. sibẹsibẹ, awọn ọjọgbọn akẹkọ nla tabi awọn ẹmi ti wọn ti ni igbala ninu ẹsẹ ti se iwadi si ti se akopọ gbogbo awọn okunagbara wọnyi si ọna mẹta, Ikini ni pe... gbogbo awọn okunagbara na ni wọn jẹ Viṣṇu-śakti. gbogbo awọn okunagbara, wọn jẹ awọn orisi agbara ti Oluwa Viṣṇu. Nisin, para ni agbara yi, to gaju. Ati kṣetra-jñākhyā tathā parā, ati awon eda, kṣetra-jña, awọn ẹda alaaye na tun jẹ agbara to ga wanti jeerisi ninu Bhagavad-gita na. A ti salaaye tẹlẹ. Awon agabra iyoku, agbara ile aye yi, ṛtīyā karma-saṁjñānyā (CC Madhya 6.154). Awọn okunagbara miiran, wọn jẹ ti ipo aimọkan. Bẹ eyinni jẹ okunagbara aye. Bẹ okunagbara aye na - ( ko daju). Ni akoko ti iku ba de a le duro boya ninu agbara ti o rẹlẹ ti aye yi, tabi ile aye yi, tabi ki a ni igbe lọ sinu agbara ti awọn aye ọrun. Eyinni jẹ bosewa. Bẹ ni Bhagavad Gita sọ pé: yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ tyajaty ante kalevaram taṁ tam evaiti kaunteya sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ

yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
tyajaty ante kalevaram
taṁ tam evaiti kaunteya
sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
(BG 8.6) .

Bayi a nsaba lero si, boya agbara aye tabi agbara ẹmi. Bayi, bawo ni a se le dari ero na? Ironu ile aye bawo ni a se le gbe ero wa lati inu agbara aye si agbara ẹmí? Bẹ na fun eronu nipa agbara mimo awọn iwe ilana Vediki wa nibẹ. Gẹgẹ bi ọpọlọpọ awọn iwe ni wọn wa fun ero ti agbara aye iwe iroyin, akọọlẹ, iwe, bẹ bẹ lọ. O kun fun iwe. Bẹ ni wọn fi ọkan wa kun fun ero ninu awọn iwe wọnyi. Bakanna, ti a ba fẹ gbe ero wa sinu agbara ẹmí, nigbana a gbọdọ rọpo wọn pẹlu awọn iwe Vediki. Nitorina, awọn ọjọgbọn nla ti kọ ọpọlọpọ awọn iwe ilana Vediki, Awọn Purāṇas ko wa lati inu igbiro; wọn jẹ awọn itan igbasilẹ. Ninu Caitanya-caritamrta ese iwe kan salaaye bayi. Anādi-bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli' gela ataeva kṛṣṇa veda-purāṇa kailā (CC Madhya 20.117). Awọn eda alãye ti wọn ni igbagbe tabi ti wọn wa ninu idé yi, wọn ti gbagbe ibasepọ wọn pẹlu Ọlọrun Ọba, ti ero awọn akitiyan aye si ti gba wọn l’ọkan. Ani ki wọn kan fi le gbe agbara iro wọn si sàkaani ọrun, Krsna-dvaipāyana Vyāsa ti fi iye ojulowo iwe ilana Vediki silẹ. Ni akọkọ o pín awọn Vedas si mẹrin. Lẹhinna o si salaye wọn ninu awọn Purāṇas. Ati fun awọn eniyan ti wọn ko l’oye pupọ bi awọn strī, śūdra, vaiśya o ti kọ Mahābhārata, O si funni ni Bhagavad Gita ninu Mahābhārata. Lẹhin na o tun fun wa ni akopọ gbogbo ilana Vediki ni soki ninu Vedanta sutra. ati fun itọnisọna l’ọjọ iwaju lori Vedanta sutra, o se àsọyé tinu-tinu ti a npe ni Śrīmad-Bhāgavatam funrarẹ.